Olori Oko Lyrics by Infinity
VERSE 1:
Hmm I have seen the future
Though I am not a prophet, hmm ah [eh]
In the book of Revelations
There is warning for the nations
He that has an ear, let him hear
What the spirit is saying [Ei]
HOOK:
Aisi n le olongbo
Loun mu eku sako
Yiyo tekun n yo
Ki ma e se tojo
Agba ki wa loja kori omo tutun wo
Fitila yi to tan
Imole wole wa
Imole ti de [Ei]
CHORUS (x4):
Olorioko shi n bo wa
On bo wa
On bo wa ye
VERSE 2:Afopinna
To loun o pa fitila
Ara re ni o pa
Se bi aaro to ba gbon, ei
L’ogun aso tele ipa, aye egbo [iye]
Afoju di omo eniyan
Olohun Oba
Iku lon mu dani
Iye iye
Ei
REPEAT HOOK
REPEAT CHORUS
REPEAT CHORUS
Aye ile, aye ile
Edumare baba
Edumare baba
Emura emura
Emura emura
Olorioko nbo o
Jagunmolu nbo o
Papa nla ti njo tohun tohun
Efufu tin mile titi
e eh
Olorioko nbo o, emura
Oba a sa ya
Oba idigbolu
eni o digbolu o asi mu wo mu womu
Lyrics found using:
- Olori oko lyrics
- infinity olori oko lyrics
- infinity ori oko lyrics
- Olori oko lyrics by infinity
- Olori oko lyrics in english
- Olorioko lericy