Kabi Osi Baba Ire ni Onise Iyanu Lyrics by PSALM EBUBE feat Pat Uwaje
Kabi Osi Baba Ire ni Onise Iyanu
……..PSALM EBUBE feat Pat Uwaje(Nig.)
Chorus
KabiO o si, Baba
Ire ni Onise iyanu
Dansaki Re, we praise You Lord
You are worthy to be praised
Somebody worship, somebody praise
(Somebody worship, somebody praise) (3x)
Baba no one like You
Chorus 1 (2x)
Who is there like You Oh Lord, oh Lord, o Lord, alleluia
Among all the gods
You reign, You reign, You reign
Chorus 1 (2x)
Oba Oba Oba Oba titi aye……Oba
Oba Oba Oba Oba Oba……Oba
Oun lo sa npese f’eye oju orun……Oba
Jesu mi o, ki ma ki n yipada……..Oba
Arabataribiti Aribitirabata……….Oba
Adagbamatepa o Arugbo Ojo Oba
Eledumare, Atererekariaye………Oba
Ajipojoikuda, Oke leyin onigbagbo…….Oba
saara Re Baba………………………Oba
Ire ma lonbamise o, to n jomi loju
Leyin Ire kosoba ti mo le sin
Oloruko nla (Oloruko repete)
Eleru niyin
Adagbamatepa o
Arugbo Ojo
Egbeega (2x)
Chorus
Otuaka chineke mudi
Agidigba eh, eh, eh, eh
Agidigba eh
Otuaka chineka idi
Agidigba eh, eh, eh, eh
Agidigba eh
Lyrics found using:
- https://www nglyrics net/kabi-osi-baba-ire-ni-onise-iyanu-lyrics-by-psalm-ebube-feat-pat-uwaje html
- Kabi osi baba lyric
- Kabiosi baba lyrics
- Lyric of kabe osi baba ti re ni onishe iyanu praise music