Aye Ole Lyrics in-Full: a Song by Infinity
Title: Aye Ole
Author: Infinity
Aye Ole Lyrics in-Full
INTRO:
hmmmm
Omo eniyan
f’eti si
oro agba, bi o she l’owuro
a she lowo ale
VERSE 1:
Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d’opin
aimola eda lo mu eda saniyan ra
olorun ti seleri, oro baba ko ni ye
Aini gbaggbao lo mu eda raropin
Bi okun n fo
Ti osa n sa
Otito wa laaye
Igbabo ni orisun ohun gbogbo
CHORUS:
Oh Hu hu hu
Aye yi ko male
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
Oh Hu hu hu
aye yi ko male o
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
Hu hu hu
Aye yi ko male
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
Oh Hu hu hu
aye yi ko male o
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
VERSE 2:
Oni suuru, ape koto je, koni jebaje
Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi
F’oju re womi ore, k’Oluwa le foju re wo e
Abiku ti d’abiye ninu aye mi
Oni suuru, ape koto je, koni jebaje
Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi
F’oju re womi ore, k’Oluwa le foju re wo e
Abiku ti d’abiye ninu aye mi
REPEAT CHORUS
VERSE 3 (x5):
Ha ha ha
Aye re ko ma ni le
To ba ba Olorun rin, o sho ri re
Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d’opin
Lyrics found using:
- aye ole lyrics
- aye ole fun eni to ba gbon
- lyrics of aye ole
- lyrics of aye ole by infinity
- infinity aye ole lyrics
- aye ole fun eni toba gbon lyrics
- aye ole fun eni to ba gbon lyrics